🎤🔥 TITLE: FROM '98 — STILL MY TIME
Intro
Badaman!
Láti '98...
Títí di 2026...
ẹjo ẹsi mi hate
Dream mi ò kú...
mo'n wa on Faith
---à a a a a a a aaaaa
badaman
Verse 1
woooo
awọn Ọ̀pọ̀ lorí ìbẹ̀rẹ̀ mi...
Diẹ̀ ninu wọ́n lorí omijé mi...
Ọ̀pọ̀ ènìyàn lóun gbọ́ orin mi...
Diẹ̀ ninu wọ́n lomọ àdúrà mi...
Mo kọ orin nígbà tí kò sí owó...
Mo kọ orin nígbà tí kò sí applause...
Mo ti kọ bars...
Kí social media tó di ọjà...
Mo ti ń lá àlá...
Kí hashtag tó di ladder...
Mo ti ń kọ verse...
Kí algorithm tó ń yan star...
Mon ghon ju mọ cassette
pelu white tv...
Mo mọ ọjọ́ CD pelu colour tv
mo'n MO ojo telephone ko to di handset
Mo ma freestyle
laye Fi agolo se drum set
Mo mọ studio tí kò ní AC
Mo mọ alẹ́ tí ebi bá mi...
Ṣùgbọ́n mo tún wọ booth...
Torí music ni ẹ̀mí mi...
---
(Bridge
mi o wá padawa fun hate
Mi ò ń chase trend...
Mo ń chase legacy...
Trend máa parí...
Legacy á wà... mi ri
---
Hook
Mo ti vibe bọ́ láti ayé '98...
Mi ò jẹ́ upcoming rapper...
Mi ò dé lánàá...
Mi ò bẹ̀rẹ̀ lónìí...
Ọ̀pọ̀ ò mọ ìtàn mi...
Wọ́n ro wipe mo'n sẹ́sẹ́ rap ni
Wọ́n ò rí gbogbo ìrìnàjò mi...
Verse 2
Ẹ má fi mí compare...
Pẹ̀lú ẹni tó ṣẹ̀ṣẹ̀ wọ game...
Game yìí ti kọ́ mi...
KẸ tó mọ orúkọ mi...
Ẹ má fi mí compare...
Pẹ̀lú Instagram numbers...
Followers lè pọ̀...
Ṣùgbọ́n character ló ń kọ history...
Ẹ má fi likes ṣe talent...
Ẹ má fi views ṣe destiny...
Àkókò Ọlọ́run...
Kò sí app tó lè speed am...
Wọ́n ní "ó pẹ́."
Mo ní "my time never expire."
Wọ́n ní "give up."
Mo ní "dream mi still on fire
---Hook
Mo ti vibe bọ́ láti ayé '98...
Mi ò jẹ́ upcoming rapper...
Mi ò dé lánàá...
Mi ò bẹ̀rẹ̀ lónìí...
Ọ̀pọ̀ ò mọ ìtàn mi...
Wọ́n ro wipe mo'n sẹ́sẹ́ rap ni
Wọ́n ò rí gbogbo ìrìnàjò mi...
Verse 3
kanipe music bá ti ń san owo bí aye ode òní...
iyẸ lọjọ́ tí mo bẹ̀rẹ̀...
Ó ṣeé ṣe kí gbogbo street...
Ti mọ orúkọ mi tán...
Ṣùgbọ́n mi ò kùnà...
Àkókò mi yàtọ̀...
Ọlọ́run louń kọ ìtàn...
Badaman