Badaman – Industry Warning (Part 3)
Badaman
Verse 1
Nínú rap yìí kì í ṣe eré, ọgbọ́n ni mo fi ń kọ
Ọ̀rọ̀ mi bí àrá ọ̀run, tí kò bá ṣọ́ra a máa fọ
Awon tí ń wa trending lórí beef ati drama
Ṣùgbọ́n talent wọn rọ bí omi inú kalabasa
Ẹ fẹ́ lo orúkọ mi ṣe ladder kí ẹ lè gòkè
Ṣùgbọ́n mo dàbí apata tí kò rọ nígbà ìjà ń de
Ọmọ, rap yìí kì í ṣe ibi tí ọmọ kékeré ti ń ṣeré
Tó bá fẹ́ wọ ogun ọrọ̀, kí o mú ìmọ̀ wá kó pé
Mo ń kọ verse bí aṣá tó ń fo lókè ọ̀run
Bar mi wuwo bí irin tí ń ṣubú láti ọ̀run
Ẹ sọ pé ẹ fẹ́ battle — ẹ jẹ́ kí talent yín hàn
Kí ẹ má ṣe dá rap rú bí ẹni tí kò mọ́ ọ̀nà
(Chorus
Badaman yàtọ̀ — ẹ mọ̀ pé a kì í ṣe mate
Ẹ má kọjá boundary bí ẹ kòba fẹ́ri wéré
Rap fún rap — jẹ́ kí ọgbọ́n yín sọ
Tí ẹ bá dákẹ́, industry yóò mọ ẹni tó sọ
Badaman yàtọ̀ — crown mi wà lórí
Kò sí rapper tó lè gba láì fi ẹ̀rí
Tí ẹ bá fẹ́ ogun ọrọ̀, ẹ wá pẹ̀lú fire
Torí verse kan lè pa career yin bí sniper
Hook
Badaman dey — thunder nínú microphone
Verse mi bí bullet tí kò mọ́ ẹnìkan own
Tó bá fẹ́ rap, rap — ma ṣe call my name
Cause when lion wake, jungle go change. 🔥
Verse 2
Nigerian emọ̀ pé rap mi jin bí ìsàlẹ̀ òkun
Ọ̀rọ̀ mi tútù bí ìrìn àjò afẹ́fẹ́ ọ̀run
Awon rapper kan fẹ́ blow nípasẹ̀ wahala
Ṣùgbọ́n orúkọ wọn rọ bí erù tí kò lórí palaba
Mo rí wọn bí ẹni tí ń sunkún to kigbè
Tí wọ́n bá rí lion, gbogbo won afi erege
Badaman kò sáré — mo ń rìn bí ọba
Tí mo bá sọ̀rọ̀ kan, gbogbo street yóò pariwo bada
Ẹyin small rapper, ẹ kọ́kọ́ lokọ́ ìmọ̀
Kí ẹ tó fẹ́ pe ara yín king nínú hip-hop ọ̀nà
Torí throne yìí kì í ṣe ti ẹni tí ń pariwo
Iwo to ye koma be industry fun blow
Chorus
Badaman yàtọ̀ — ẹ mọ̀ pé a kì í ṣe mate
Ẹ má kọjá boundary bí ẹ kòba fẹ́ri wéré
Rap fún rap — jẹ́ kí ọgbọ́n yín sọ
Tí ẹ bá dákẹ́, industry yóò mọ ẹni tó sọ
Badaman yàtọ̀ — crown mi wà lórí
Kò sí rapper tó lè gba láì fi ẹ̀rí
Tí ẹ bá fẹ́ ogun ọrọ̀, ẹ wá pẹ̀lú fire
Torí verse kan lè pa career yin bí sniper
Bridge
Ẹ gbọ́ dáadáa — rap yìí kì í ṣe play
Real MC mọ code tí game yìí n pe
Respect ni key, talent ni door