[Intro]
Intro - abidémi Bamiss Ogo ibilè
Éjẹ́ k’a dákẹ́ fún ìṣẹ́jú kan…
Faisons silence saints majestueux onitakon ÓBA ADÉRÔBIOJO ILUFÈMILOYE
Ọjọ́ burúkú ní ọ̀nà Katagon, ìmọ́lẹ̀ rẹ kú
Le jour maudit sur la route de Katagon, ta lumière s’est éteinte
[Verse 1]
Ìjàmbá gbá ọ lọ, Takon wọ̀ ní òkùnkùn
L’accident t’a emporté, Takon s’est habillé de ténèbres
[Verse 2]
Owolabi Adissa, ọmọ OBÉ, Agbola
Owolabi Adissa, fils OBÉ, membre du groupe Agbola
[Verse 3]
Agbolajoyé ń sunkún, Erin ló akôgoun lô
Agbolajoyé pleure, un bon enfant est parti
[Pre-Chorus]
Iyawo rẹ dákẹ́, ẹkún kún ojú ọmọ rẹ
Ta femme est sans voix, les larmes remplissent les yeux de tes enfants
[Pre-Chorus]
Ẹ̀gbọ́n àti àbúrò, ọ̀rẹ́ rẹ, gbogbo wọn kò lágbára
Frères et sœurs, tes amis, tous sont sans force
[Pre-Chorus]
Àwọn ọdọ ilú, àgbà àti kékeré, ń ké “Owolabi”
Les jeunes du village, grands et petits, crient “Owolabi”
[Chorus]
Sun re o, Owolabi, ọmọ ogbón ilẹ̀ Takon
Dors en paix, Owolabi, génie de la terre de Takon