TITLE: STREET PROPHET
Intro
Badaman...
Ẹni tí ayé kọ...
Ló ń sọ òtítọ́...
Street Prophet...
Ẹ gbọ́ mi dáadáa...
---
Hook
Street Prophet...
Mi ò ń ta iro...
Mo ń ta òtítọ́...
Street Prophet...
Mo fi ìrírí kọ orin...
Kì í ṣe ìrò.
Mo rí ayé...
Ayé sì rí mi...
Gbogbo line mi...
Kún fún ìtumọ̀...
---
Verse 1
Mo rí ebi tó ń pa ìrètí...
Mo rí owó tó ń yí ènìyàn padà...
Mo rí fake smile...
Mo rí love tó ní condition...
Ọ̀pọ̀ wọ funfun...
Ṣùgbọ́n ọkàn wọn dúdú...
Ọ̀pọ̀ ń sọ pé,
"Mo wà pẹ̀lú rẹ."
Tí wahala dé...
Gbogbo wọn di stranger...
Mi ò kọ orin láti mú hype...
Mo kọ orin kí ọkàn jí...
Kí ẹni tó fẹ́ juwọ́ sílẹ̀...
Tun rí ìdí láti dìde...
---
Bridge
Ẹ gbọ́ mi...
Kí ẹ má gbọ́ ariwo...
Ẹ wo iṣẹ́...
Kí ẹ má wo package...
Àkókò ló máa dá gbogbo wa lẹ́jọ́...
---
Hook
Street Prophet...
Mi ò ń ta iro...
Mo ń ta òtítọ́...
Street Prophet...
Mo fi ìrírí kọ orin...
Kì í ṣe ìrò.
Mo rí ayé...
Ayé sì rí mi...
Gbogbo line mi...
Kún fún ìtumọ̀...
Verse 2
,
badaman
Àgbà ní...
Ọ̀rọ̀ òtítọ́ kì í tán lójú ọjà...
Mo fẹ́ kí rap mi...
Di ohùn àwọn tí kò lè sọ̀rọ̀...
Kí verse mi...
Di fitilà nínú òkùnkùn...
Kí message mi...
Má bàjẹ́ pẹ̀lú àkókò...
Mi ò fẹ́ trend fún ọjọ́ kan...
Mo fẹ́ kí orúkọ mi...
Dúró pẹ̀lú ìtumọ̀...
---
Drill Chant
If tomorrow call my name...
Make my music answer...
If my journey inspire one soul...
Then my work no waste...
I came from silence...
I'm chasing legacy...
Not just fame...
But impact...
Every verse...
Na footprint...
Every song...
Na message...
Street Prophet!
Street Prophet!
---
Hook
Street Prophet...
Mi ò ń ta iro...
Mo ń ta òtítọ́...
Street Prophet...
Mo fi ìrírí kọ orin...
Kì í ṣe ìrò.
Mo rí ayé...
Ayé sì rí mi...
Gbogbo line mi...
Kún fún ìtumọ̀...
Outro
Mi ò jẹ́ prophet...
Tó ń sọ ọjọ́ ọ̀la...
Ṣùgbọ́n...
Mo jẹ́ ẹni tó ń sọ...
Pé sùúrù ní í bí ọlá...
Pé iṣẹ́ ló ń bí àṣeyọrí...
Pé ìwà rere...
Ló ń jẹ́ kí orúkọ má kú...
Street Prophet...
Voice of the street