[Intro]
Bouger, bouger, laissez le groove bouillonner dans le cœur
Tambours martèlent, cuivres flamboyent, la fête commence
[Verse 1]
Mama monifẹ rẹ lọpọ lori ile alaye iku ojiji o
(2)nipa jẹun ọmọ laye rẹ oju koju to ba fẹ wu ẹ oju naa yoo fọ lojiji iṣuu ọmọ yoo jinna fun [ẹjẹ iyaami to nifẹ mi to loyun mi fun oṣu ]
mẹsan tosi pọ mi fun ọdun mẹta mọ yinwọ eleda mi yoo pese fun e orukọ iya mi [gbenou Josephine]
eni lọjọ ẹyin mama a ṣe yi ṣamọdun wa jẹ ọmọ laaye rẹ wa pẹpẹpẹ a wa ọmọ rẹ a si lowo lọwọ a le fi owo tun aaye rẹ ṣe iya mi
[gbenou Josephine]igba ọdun kan ni o ni fojusun ku awọn ọmọ rẹ..