🎤 WON NI RAP TI DIE NAIJA
intro)
Yankee badaman mo'n ti so wipe
Return of badaman Kise báwa ṣaba
yeba
Wọ́n ní rap ti kú — mo ní ta ló sin?
everybody sit well and listen
Mo tún jí i dide, mo fi pen ṣe resurrection.
Wọ́n ń wá attention, mo ń kọ́ direction,
Mo rí future nínú pain — that's my prediction.
Ọ̀rọ̀ mi kì í wọ̀lé lasan, ó máa jókòó,
Bar kọọkan ní meaning, kí brain rẹ lè ṣiṣẹ́ mató
Mo sọ díẹ̀, ṣùgbọ́n meaning yen náà jin,
Bí o bá fẹ́ de code mi, o gbọ́dọ̀ rewind.
Mo wá láti Korope, mo mọ̀ ìyà,
Kò sí private jet, ṣùgbọ́n vision ń fò gíga.
Mama mi gbàdúrà, mo gbé e sí ọkàn,
Tí ilẹ̀kùn bá ti, mo máa yọ́ ọ̀nà.
Mo kó gbogbo scar, mo kó gbogbo lesson,
Mo fi struggle ṣe school, mo fi hunger ṣe session.
Wọ́n rí poverty, mo rí preparation,
Wọ́n rí failure, mo rí transformation.
Yoruba l'ẹnu mi, but the vision international,
Street gave me grammar, pain made me intellectual.
Mo ń rhyme ìyà / ìlà / ìran / ìrà,
Mo ń kọ́ orin tí ọjọ́ iwájú máa rántí.
Mo ní vision tó jin ju ojú lọ,
Mo ní message tó wuwo ju voice lọ,
Mo ní dream tó ga ju roof lọ,
Tí wọn bá fẹ́ mọ̀ ibi tí mo ń lọ —
Ẹ jẹ́ kí iṣẹ́ mi sọ.
Mo kọ́ orúkọ mi sínú verse, not graffiti,
Ọ̀la máa judge everybody, time no pity.
Mi ò bẹ̀rù ẹni tó ń ṣiyèméjì,
Nítorí doubt wọn kò lè pa destiny.
Rap mi kì í ṣe noise, ó jẹ́ evidence,
Every pain I survived gave the pen confidence.
Mo ń sọ truth with a dark ambience,
Badaman in the booth — pure intelligence.
Wọ́n ní “who be this?” — Yankee Badaman,
Ọmọ street tó yí struggle sí curriculum.
Mo fẹ́ kí ọmọ tó ń sunkún gbọ́ ohun mi,
Kí ó mọ̀ pé òru kì í pé títí
Mo ti kọjá ibi tí mo le fẹ́ juwọ́ sílẹ̀,
Mo ti rí ọjọ́ tí hope fẹ́ sọnù.síbẹ̀
Ṣùgbọ́n mo pa dream mọ́ bí secret,
Mo fi gbogbo ìrora sí microphone —
now the whole world go hear it.
Wọ́n ní rap ti kú Naija...
Mo ní rap ń bẹ nínú wa.
Mo kan wá láti tú un síta.
badaman just wake from dream
lati odun nineteen ninety eight
ti 80 % bati like 20% fuckin your hate