Intro - abidémi Bamiss Ogo ibilè
Ẹjẹ́ k’a dákẹ́ fún ìṣẹ́jú kan…
Faisons silence saints majestueux onitakon ÓBA ADÉRÔBIOJO ILUFÈMILOYE
Ọjọ́ burúkú ní ọ̀nà Katagon, ìmọ́lẹ̀ rẹ kú
Le jour maudit sur la route de Katagon, ta lumière s’est éteinte
Ìjàmbá gbá ọ lọ, Takon wọ̀ ní òkùnkùn
L’accident t’a emporté, Takon s’est habillé de ténèbres
Owolabi Adissa, ọmọ OBÉ, Agbola
Owolabi Adissa, fils OBÉ, membre du groupe Agbola
Agbolajoyé ń sunkún, Erin ló akôgoun lô
Agbolajoyé pleure, un bon enfant est parti
Pré-Refrain
Iyawo rẹ dákẹ́, ẹkún kún ojú ọmọ rẹ
Ta femme est sans voix, les larmes remplissent les yeux de tes enfants
Ẹ̀gbọ́n àti àbúrò, ọ̀rẹ́ rẹ, gbogbo wọn kò lágbára
Frères et sœurs, tes amis, tous sont sans force
Àwọn ọdọ ilú, àgbà àti kékeré, ń ké “Owolabi”
Les jeunes du village, grands et petits, crient “Owolabi”
Refrain - Chœur doux + Lead R&B
Sun re o, Owolabi, ọmọ ogbón ilẹ̀ Takon
Dors en paix, Owolabi, génie de la terre de Takon
Láti Sakete sí Takon, ayita de iyoko amouroko de katagon Misérété sí Avrankou
De Sakete à Takon, de Misérété à Avrankou
Porto Novo àti Cotonou, gbogbo ayé ń sunkún fún ọ
Porto-Novo et Cotonou, akpakpa complet le monde entier pleure pour toi
Ìwọ ni ìràwọ̀ tí kò ní pa, nínú ọkàn wa
Tu es l’étoile qui ne s’éteint pas, dans nos cœurs
Bamiss ń kéde pé: “Mo nífẹ̀ rẹ, mi ò ní gbàgbé rẹ láé”
Bamiss déclare : “Je t’aime, je ne t’oublierai jamais”
Couplet 2
Ìwọ tí o jẹ́ ìrètí fún ẹgbẹ́ Agbola
Toi qui étais l’espoir du groupe Agbola
Ọwọ́ rẹ ṣí sílẹ̀ fún gbogbo ènìyàn ní Takon
Tes mains étaient ouvertes pour tout le monde à Takon
Ṣùgbọ́n ikú ò bìkítà, ó ya ọ kúrò lójijì
Mais la mort n’a pas pitié, elle t’a arraché soudainement
Nísisìyí ilé OBÉ di ilé ẹ̀kún
Maintenant la maison OBÉ est devenue une maison de pleurs
Ṣùgbọ́n orúkọ rẹ yóò máa gbe’ni ró, bí orin
Mais ton nom nous apaisera toujours, comme une chanson
Pont - Traditionnel, gangan + voix seule